Limit this search to....

Ológbò Olùwòsàn Náà: Yorùbá Edition of The Healer Cat Softcover Edition
Contributor(s): Pere, Tuula (Author), Bezak, Klaudia (Illustrator), Agboọla ́, Ṣọla&# (Translator)
ISBN: 9523571249     ISBN-13: 9789523571242
Publisher: Wickwick Ltd
OUR PRICE:   $11.61  
Product Type: Paperback
Language: Yoruba
Published: July 2019
Qty:
Additional Information
BISAC Categories:
- Juvenile Fiction | Animals - Cats
- Juvenile Fiction | Action & Adventure - Survival Stories
- Juvenile Fiction | Science & Nature - Weather
Physical Information: 0.11" H x 8" W x 10" (0.28 lbs) 40 pages
 
Descriptions, Reviews, Etc.
Publisher Description:

Celesse, the healer cat, is a highly respected member of the neighborhood. As the mistress's favorite cat, she spends lazy days in the warmth of the house.
One snowy night a mother hare rushes in, desperate for help. Reluctantly, the healer cat travels with her through a nighttime snowstorm and biting cold winds. In a dark forest, Celesse comes face-to-face with a scary surprise and is forced to gather her powers for the first time in a while.
---
Nítorí ẹ̀bùn rẹ̀, Celesse ológbò olùwòsàn jẹ́ ẹni tí a pọ́nlé gidi ní àdúgbò rẹ̀. Gẹ́gẹ́ bí ààyò fún ìyá àgbà, ó fẹ́ràn láti máa gbádùn àkókò tí kò bá níṣẹ́ nínú ilé rẹ̀.
Ṣùgbọ́n nígbà náà, ìyá ehoro kan wọlé, tí ó nbéèrè fún ìrànlọ́wọ́. Ìtẹnumọ́ rẹ̀ borí ìlọ́ra ti ológbò olùwòsàn, tí ó nmú u là yìnyín líle kọjá. Nínú igbó dúdú kan, Celesse dojúkọ ìyanu kan, èyí tí ó mú kí ó súnrakì.
Ní kété tí òru náà àti ìrìnàjò náà parí, oòrùn jáde, èyí tí ó fà ìlọ́wọ́wọ́ sórí àwọn ewéko àti sí ọkàn ológbò olùwòsàn.